Iṣe Apo 28:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awa si de Romu, balogun ọrún fi awọn ondè le olori ẹṣọ́ lọwọ: ṣugbọn nwọn jẹ ki Paulu ki o mã dagbe fun ara rẹ̀ pẹlu ọmọ-ogun ti ṣọ́ ọ.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:15-23