Iṣe Apo 27:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ keji awa de Sidoni. Juliu si ṣe inu rere si Paulu, o si bùn u láye ki o mã tọ̀ awọn ọrẹ́ rẹ̀ lọ lati ri itọju.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:1-8