Iṣe Apo 26:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu rẹ̀ na bi mo ti nlọ si Damasku ti emi ti ọlá ati aṣẹ ikọ̀ lati ọdọ awọn olori alufa lọ,

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:9-21