Iṣe Apo 26:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbapipọ ni mo ṣẹ́ wọn niṣẹ ninu gbogbo sinagogu, mo ndù u lati mu wọn sọ ọrọ-odi; nigbati mo ṣoro si wọn gidigidi, mo ṣe inunibini si wọn de àjeji ilu.

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:3-13