Iṣe Apo 25:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si de, awọn Ju ti o ti Jerusalemu sọkalẹ wá duro yi i ká, nwọn nkà ọ̀ran pipọ ti o si buru si Paulu lọrùn, ti nwọn kò le ladi.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:1-9