Iṣe Apo 25:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si gbe ãrin wọn ju ijọ mẹjọ tabi mẹwa lọ, o sọkalẹ lọ si Kesarea; ni ijọ keji o joko lori itẹ́ idajọ, o si paṣẹ pè ki a mu Paulu wá.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:1-13