Iṣe Apo 24:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si paṣẹ fun balogun ọrún kan pe, ki o mã ṣe itọju Paulu, ki o si bùn u làye, ati pe ki o máṣe dá awọn ojulumọ̀ rẹ̀ lẹkun, lati ma ṣe iranṣẹ fun u.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:17-27