Iṣe Apo 24:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Feliksi gbọ́ nkan wọnyi, oye sa ye e li ayetan nipa Ọna na; o tú wọn ká na, o ni, Nigbati Lisia olori ogun ba sọkalẹ wá, emi o wadi ọ̀ran nyin daju.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:18-27