Iṣe Apo 23:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ilẹ mọ́, awọn Ju kan dimọlu, nwọn fi ara wọn bu pe, awọn kì yio jẹ bẹ̃li awọn kì yio mu, titi awọn ó fi pa Paulu.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:10-13