Iṣe Apo 23:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li oru ijọ na Oluwa duro tì i, o si wipe, Tujuka: nitori bi iwọ ti jẹri fun mi ni Jerusalemu, bẹ̃ni iwọ kò le ṣaijẹrí ni Romu pẹlu.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:7-15