Iṣe Apo 22:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ keji, nitoriti o fẹ mọ̀ dajudaju ohun ti awọn Ju nfi i sùn si, o tú u silẹ, o paṣẹ ki awọn olori alufa ati gbogbo igbimọ pejọ, o si mu Paulu sọkalẹ, o si mu u duro niwaju wọn.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:28-30