Iṣe Apo 22:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn ti o mura lati bi i lẽre kuro lọdọ rẹ̀: lojukanna olori-ogun pẹlu si bẹ̀ru, nigbati o mọ̀ pe ara Romu ni iṣe, ati nitori o ti dè e.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:20-30