Iṣe Apo 22:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi nwọn si ti fi ọsán dè e, Paulu bi balogun ọrún ti o duro tì i pe, O ha tọ́ fun nyin lati nà ẹniti iṣe ará Romu li aijẹbi?

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:18-30