Iṣe Apo 22:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olori ogun paṣẹ pe ki a mu u wá sinu ile-olodi, o ni ki a fi ẹgba bi i lẽre; ki on ki o le mọ̀ itori ohun ti nwọn ṣe nkigbe le e bẹ̃.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:18-25