Iṣe Apo 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si ta ẹ̀jẹ Stefanu ẹlẹri rẹ silẹ, emi na pẹlu duro nibẹ̀, mo si li ohùn si ikú rẹ̀, mo si nṣe itọju aṣọ awọn ẹniti o pa a.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:15-23