Iṣe Apo 22:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si wipe, Oluwa, awọn pãpã mọ̀ pe, emi a ti mã sọ awọn ti o gbà ọ gbọ sinu tubu, emi a si mã lù wọn ninu sinagogu gbogbo:

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:15-24