Iṣe Apo 20:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ mã ṣọra, ki ẹ si mã ranti pe, fun ọdún mẹta, emi kò dẹkun ati mã fi omije kìlọ fun olukuluku li ọsán ati li oru.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:21-36