Iṣe Apo 20:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati larin ẹnyin tikaranyin li awọn enia yio dide, ti nwọn o ma sọ̀rọ òdi, lati fà awọn ọmọ-ẹhin sẹhin wọn.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:29-32