Iṣe Apo 20:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si tún gòke lọ, ti o si bù akara, ti o si jẹ, ti o si sọ̀rọ pẹ titi o fi di afẹmọjumọ́, bẹ̃li o lọ.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:4-12