Iṣe Apo 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Paulu si sọkalẹ, o wolẹ bò o, o gbá a mọra, o ni, Ẹ má yọ ara nyin lẹnu; nitori ẹmí rẹ̀ mbẹ ninu rẹ̀.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:1-13