Iṣe Apo 19:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ilu na si kún fun irukerudò: nwọn fi ọkàn kan rọ́ sinu ile ibĩṣire, nwọn si mu Gaiu ati Aristarku ara Makedonia, awọn ẹgbẹ ajọrin Paulu.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:23-34