Iṣe Apo 19:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn gbọ́ ọ̀rọ wọnyi, nwọn kún fun ibinu, nwọn kigbe, wipe, Oriṣa nla ni Diana ti ara Efesu.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:19-38