Iṣe Apo 17:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paulu si dide duro larin Areopagu, o ni, Ẹnyin ará Ateni, mo woye pe li ohun gbogbo ẹ kun fun oniruru isin ju.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:12-28