Iṣe Apo 17:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori gbogbo awọn ará Ateni, ati awọn alejò ti nṣe atipo nibẹ kì iṣe ohun miran jù, ki a mã sọ tabi ki a ma gbọ́ ohun titun lọ.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:14-23