Iṣe Apo 17:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mu u, nwọn si fà a lọ si Areopagu, nwọn wipe, A ha le mọ̀ kili ẹkọ́ titun ti iwọ nsọrọ rẹ̀ yi jẹ́.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:18-22