Iṣe Apo 17:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu awọn Epikurei pẹlu, ati awọn ọjọgbọ́n Stoiki kótì i. Awọn kan si nwipe, Kili alahesọ yi yio ri wi? awọn miran si wipe, O dabi oniwasu ajeji oriṣa: nitoriti o nwasu Jesu, on ajinde fun wọn.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:10-23