Iṣe Apo 16:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojiji iṣẹlẹ nla si ṣẹ̀, tobẹ̃ ti ipilẹ ile tubu mi titi: lọgan gbogbo ilẹkun si ṣí, ìde gbogbo wọn si tu silẹ.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:22-28