Iṣe Apo 16:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn larin ọganjọ Paulu on Sila ngbadura, nwọn si nkọrin iyìn si Ọlọrun: awọn ara tubu si ntẹti si wọn.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:23-33