Iṣe Apo 15:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Ọlọrun, ti iṣe olumọ-ọkàn, o jẹ wọn li ẹrí, o nfun wọn li Ẹmí Mimọ́, gẹgẹ bi awa:

Iṣe Apo 15

Iṣe Apo 15:6-18