Iṣe Apo 13:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi nwọn si ti njọsìn fun Oluwa, ti nwọn si ngbàwẹ, Ẹmí Mimọ́ wipe, Ẹ yà Barnaba on Saulu sọtọ̀ fun mi fun iṣẹ ti mo ti pè wọn si.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:1-9