Iṣe Apo 13:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN woli ati awọn olukọni si mbẹ ninu ijọ ti o wà ni Antioku; Barnaba, ati Simeoni ti a npè ni Nigeri, ati Lukiu ara Kirene, ati Manaeni, ti a tọ́ pọ̀ pẹlu Herodu tetrarki, ati Saulu.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:1-7