Iṣe Apo 12:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli na si wi fun u pe, Di àmure, ki o si so salubàta rẹ. O si ṣe bẹ̃. O si wi fun u pe, Da aṣọ rẹ bora, ki o si mã tọ̀ mi lẹhin.

Iṣe Apo 12

Iṣe Apo 12:6-18