Iṣe Apo 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si wo o, angẹli Oluwa duro tì i, imọlẹ si mọ́ ninu tubu: nigbati o si lù Peteru pẹ́pẹ li ẹgbẹ o ji i, o ni, Dide kánkan. Ẹwọn rẹ̀ si bọ́ silẹ kuro lọwọ rẹ̀.

Iṣe Apo 12

Iṣe Apo 12:1-15