Iṣe Apo 12:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI akoko igbana ni Herodu ọba si nawọ́ rẹ̀ lati pọn awọn kan loju ninu ijọ.

2. O si fi idà pa Jakọbu arakunrin Johanu.

3. Nigbati o si ri pe, o dùnmọ awọn Ju, o si nawọ́ mu Peteru pẹlu. O si jẹ ìgba ọjọ àiwukàra.

Iṣe Apo 12