Iṣe Apo 11:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sọ fun wa bi on ti ri angẹli kan ti o duro ni ile rẹ̀, ti o si wipe, Ranṣẹ lọ si Joppa, ki o si pè Simoni ti apele rẹ̀ jẹ Peteru;

Iṣe Apo 11

Iṣe Apo 11:4-14