Iṣe Apo 11:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹmí si wi fun mi pe, ki emi ki o ba wọn lọ, ki emi máṣe kọminu ohunkohun. Awọn arakunrin mẹfa wọnyi si ba mi lọ, a si wọ̀ ile ọkunrin na:

Iṣe Apo 11

Iṣe Apo 11:8-19