Iṣe Apo 10:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nijọ keji nwọn si wọ̀ Kesarea. Korneliu si ti nreti wọn, o si ti pè awọn ibatan ati awọn ọrẹ́ rẹ̀ timọtimọ jọ.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:16-32