Iṣe Apo 10:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o pè wọn wọle, o si fi wọn wọ̀. Nijọ keji o si dide, o ba wọn lọ, ninu awọn arakunrin ni Joppa si ba a lọ.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:22-28