1. Tes 2:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awa fẹ lati tọ̀ nyin wá, ani emi Paulu lẹ̃kini ati lẹ̃keji; Satani si dè wa li ọ̀na.

1. Tes 2

1. Tes 2:14-19