1. Tes 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn, ará, awa ti a gbà kuro lọdọ nyin fun sã kan li ara, ki iṣe li ọkàn, pẹlu itara ọpọlọpọ li awa ṣe aniyan ti a si fẹ gidigidi lati ri oju nyin.

1. Tes 2

1. Tes 2:9-20