1. Sam 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ara Aṣdodu ji li owurọ ọjọ keji, kiye si i, Dagoni ti ṣubu dojubolẹ niwaju apoti Oluwa. Nwọn si gbe Dagoni, nwọn si tun fi i si ipò rẹ̀.

1. Sam 5

1. Sam 5:1-9