1. Sam 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn Filistini gbe apoti Ọlọrun, nwọn si gbe e wá si ile Dagoni, nwọn gbe e kà ilẹ li ẹba Dagoni.

1. Sam 5

1. Sam 5:1-11