1. Sam 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ̀ru si ba awọn Filistini, nwọn si wipe, Ọlọrun wọ budo. Nwọn si wipe, Awa gbe! nitoripe iru nkan bayi kò si ri.

1. Sam 4

1. Sam 4:3-9