1. Sam 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn Filistini si gbọ́ ohùn ariwo na, nwọn si wipe, Ohùn ariwo nla kili eyi ni budo awọn Heberu? O si wa ye wọn pe, apoti majẹmu Oluwa li o de budo.

1. Sam 4

1. Sam 4:1-16