1. Sam 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun Samueli pe, Kiyesi i, emi o ṣe ohun kan ni Israeli, eyi ti yio mu eti mejeji olukuluku awọn ti o gbọ́ ọ ho.

1. Sam 3

1. Sam 3:4-20