1. Sam 3:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa wá, o si duro, o si pè bi igbá ti o kọja, Samueli, Samueli. Nigbana ni Samueli dahun pè, Ma wi; nitori ti iranṣẹ rẹ ngbọ́.

1. Sam 3

1. Sam 3:1-16