1. Sam 23:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si mọ̀ pe Saulu ti gbèro buburu si on; o si wi fun Abiatari alufa na pe, Mu efodu na wá nihinyi.

1. Sam 23

1. Sam 23:8-10