1. Sam 23:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wipe Oluwa Ọlọrun Israeli, lõtọ ni iranṣẹ rẹ ti gbọ́ pe Saulu nwá ọ̀na lati wá si Keila, lati wá fọ ilu na nitori mi.

1. Sam 23

1. Sam 23:6-20