1. Sam 13:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo Israeli si gbọ́ pe Saulu pa ẹgbẹ ogun awọn Filistini, Israeli si di irira fun awọn Filistini. Awọn enia na si pejọ lẹhin Saulu lati lọ si Gilgali.

1. Sam 13

1. Sam 13:1-8