1. Sam 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jonatani si pa ẹgbẹ ogun awọn Filistini ti o wà ninu ile olodi ni Geba, awọn Filistini si gbọ́. Saulu fun ipè yi gbogbo ilẹ na ka, wipe, Jẹ ki awọn Heberu gbọ́.

1. Sam 13

1. Sam 13:1-8